1 Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú
Àwọn àlàyé wọ̀nyìí máa fún wa ni ìgbékalẹ̀ àdírẹẹẹ̀sì ìfẹnukò.
2 IPv6 àdírẹ́ẹ̀sì
Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 wà lórí bíìtì 128 fún àwọn atọ́kùn.
Irúfẹ́ àdírẹ́ẹ̀sì atọ́kùn mẹ́ta ló wà :
  1. Unicast : Àdírẹ́ẹ̀sì ìtànkalẹ̀ fún ojú kan
    Máa ń tọ́ka sí atọ́kùn kan, èdìdì tí a bá firánṣẹ́ pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì unicast máa
    dórí atọ́kùn ìtọ́kasí.
  2. Αnycast : Àdírẹ́ẹ̀sì ìtànkalẹ̀ ojú kan nínú púpọ̀
    Máa tọ́ka sí àwọn ìjọ atọ́kùn (àwọn atọ́kùn ti kókó kan tí wọn sì yàtọ̀ ).
    Èdìdì tí a bá firánṣẹ́ sí àdírẹ́ẹ̀sì anycast kan máa dórí atọ́kùn tí kò jìnà,
    alànà ló máa ṣedíwọ̀n ọnà yìí.
  3. Multicast : Ìtànkalẹ̀
    Máa tọ́ka sí ìjọ àwọn atọ́kùn ( wọ́n wà nínú àwọn kókó tó yàtọ̀ ).
    Èdìdì tí a bá firánṣẹ́ pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì multicast máa dórí àwọn atọ́kùn wọ̀nyìí.
    Kò sí àdírẹ̀ẹ̀sì ìtànkalẹ̀ gbogbogbò pẹ̀lú IPv6, a parọ iṣẹ́ wọn pẹ́lú àdírẹ́ẹ̀sì multicast. Nínú IPv6 àwọn òdo àti àwọn oókan jẹ́ àwọn oǹkaye tó bá òfin mú fún gbogbo ààyè.
2.1 Àwòṣe ìlò àdírẹ́ẹ̀sì
Àwọn atọ́kùn ni a máa ń lò àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 fún, a kìí lò wọn fún àwọn kókó àsopọ̀.
Àdírẹ́ẹ̀sì unicast máa tọ́ka sí atọ́kùn kan tó wà nínú kókó kan, tó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn atọ́kùn kókó náà, a lè lò àdírẹ́ẹ̀sì unicast kan fi ṣàfidámọ̀ kókó náà.
Gbogbo àwọn atọ́kùn ní láti ní àdírẹ́ẹ̀sì unicast kan tó jẹ́ àsopọ̀ agbègbè, a lè fún atọ́kùn ni àdírẹ́ẹ̀sì kan; a lè fún un ni àdírẹ́ẹ̀sì méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, ti irúfẹ́ wọn yàtọ̀ ( unicast, anycast, multicast ) tàbí pẹ̀lú iyekíye oǹkaye fífò.
Nígbà tí òpin àwọn àdírẹ́ẹ̀sì unicast bá jù ti agbègbè lọ, kò pọndandan ká fún atọ́kùn kan ni àdírẹ́ẹ̀sì yìí tí kìí bá ṣe ti  èdìdì tó kúrò tàbí tí ń lọ sí agbègbè tí kìí ṣe ti ẹgbẹ́. Èyí máa wúlò nígbà mì ín fún àsopọ̀ ojú-àmì sí ojú-àmì. Àmọ́ sùgbọ́n kan wà níbẹ̀ :
IPv6 jẹ́ ìtẹ̀síwájú  IPv4 tí àfòmọ́ àsopọ̀ abẹ́nu somọ́ àsopọ̀ kan. Àwọn àfòmọ́ alásopọ̀ abẹ́nu púpọ̀ lè wà ni sísopọ̀ mọ́ àsopọ̀ kan.
2.2  Kíkọ àyọkà àdírẹ́ẹ̀sì
Ọ̀nà mẹ́ta ni a máa ń ṣàfihàn àyọkà àdírẹ́ẹ́sì IPv6.
ìrísí tí a máa ń lò ni :
1)   X:X:X:X:X:X:X:X tí àwọn X jẹ́ oǹkaye oní mẹ́rindínlógun pẹ̀lú bíìtì 16.
Àpẹẹrẹ
FEDC:BΑ98:7654:3210:FDEC:BΑ98:7654:3210
1080:0:0:0:8:800:200C:417Α
Kìí ṣe dandan ká kọ àwọn òdo tí kò níí ìtúmọ̀ sínú àwọn ààyè kọ̀ọ̀kan , àmọ́ oǹkaye kan láti wà nínú ààyè kọ̀ọ̀kan.
2)         Ọ̀nà ti a fi kọ àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 máa ń gùn jù, nígbà gbogbo tí àwọn 0 bá wà láàrin àyọkà àdírẹ́ẹ̀sì yìí a máa lò àmi :: fi ṣèfúnpọ̀ àyọkà yìí. “: :” túmọ̀ sí bíìtì 16 tó dọ́gba mọ́ 0, ẹ̀kan ni “: :” lè wà nínú àdírẹ́ẹ̀sì. Α tún lè lò “: :” fi ṣèfúnpọ̀ àwọn 0 tí ìbẹ̀rẹ̀ àti ti ìkẹ́yìn.
Àpẹẹrẹ
1080:0:0:0:8:800:200C:417Α                          Àdírẹ́ẹ̀sì   IP
FF01:0:0:0:0:0:0:101                                       Àdírẹ́ẹ̀sì   multicast
0:0:0:0:0:0:0:1                                                 Àdírẹ́ẹ̀sì  Ìpari c
òpin
0:0:0:0:0:0:0:0                                                 Àdírẹ́ẹ̀sì
Α tún lè kọ wọn lọ́nà yìí :
1080::8:800:200C:417Α
FF01:0:101
::1
::
3)     Fún lílò àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 lọ́nà ìdàpọ̀ IPv6 àti IPv4 a máa lò kíkọ yìí
X:X:X:X:X:X:d:d:d:d tí “X” jẹ́ oǹkaye onímẹ́rindínlógun tí d sì jẹ́ oǹkaye tí a máa lò pẹ̀lú IPv4 ( oǹkaye  oníwẹ́wa )
Àpẹẹrẹ
0:0:0:0:0:0:13.1.68.3
0:0:0:0:0:FFFF:129.144.52.38     tàbí
::13.1.68.3
::FFFF:129.144.52.38
2.3  Àyọkà tí a sàfihàn pẹ̀lú àfomọ́ àdírẹ́ẹ̀sì                                                                                                 
Α máa ń ṣàfihàn àyọkà àdírẹ́ẹ̀sì àfòmọ́ IPv6 bí a tí ń kọ ti  IPv4 lọ́nà CIDR.
Ìrísí :
Àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 / gígùn àfòmọ́ :
Àdírẹ́ẹ̀sì ipv6  :  Àwọn èyí tí a rí lókè
Gígùn àfòmọ́  :  Oǹkaye onímẹ́wa tí ń tọ́ka sí iye bíìtì agbègbè tó wà ni sísopọ̀ tí ń
fi àfòmọ́ hàn.
Àwọn àpẹẹrẹ tó wà nísàlẹ́ jẹ́ àfihàn àfòmọ́ oní bíìtì 60 tó bá òfin mu :
Àfòmọ́  12B000000000CD3
12ΑB:0000:0000:CD3:0000:0000:0000:0000/60
12ΑB:0:0:CD3::/60
Àwọn kíkọ wọ̀nyìí ò bófin mu :
12ΑB:0:0:CD3/60
12ΑB::CD30 /60
12ΑB::CD3/60
Nígbà tí a bá fẹ́ kọ àdírẹ́ẹ̀sì kókó pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì àfòmọ́ kókó yìí ( bíi àpẹẹrẹ àlásopọ̀ abẹ́nu ) a lè kọ méjèjì báyìí :
Àdírẹ́ẹ̀sì kókó                12ΑB:0:0:CD30:123:4567:89ΑB:CDEF
alásopọ̀ abẹ́nu                12ΑB:0:0CD30::/60
Ní ṣokí                           12ΑB:0:0:CD30:123:4567:89B:CDEF / 60
2.4 Ìṣàfihàn àdírẹ́ẹ̀sì àkànṣe
Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì àkànṣe máa  ń tọ́ka sí àwọn bíìtì nínú àdírẹ́ẹ̀sì. Àwọn ààyè tí àwọn bíìtì wọ̀nyìí  wà nínú wọn ni a ń pè ni ìrísí Àfòmọ́ (FP ), àwọn kíkọ wọn ni wọ̀nyìí.
Ìpín                                                                   Àfòmọ́                    Àjákù
( àbéjì  )            ( ààyè àdírẹ́ẹ̀sì )
    Ìfipamọ                               0000 0000      1/256
    Àìmúlò                                0000 0001      1/256
 
    Ìfipamọ fún Ìpín NSAP                 0000 001       1/128
    Ìfipamọ fún Ìpín IPX                  0000 010       1/128
 
    Àìmúlò                                0000 011       1/128
    Àìmúlò                                0000 1         1/32
    Àìmúlò                                0001           1/16
 
    Àdírẹ́ẹ̀sì káríayé Unicast Αlápàpọ̀      001            1/8
    Àìmúlò                                010            1/8
    Àìmúlò                                011            1/8
    Àìmúlò                                100            1/8
    Àìmúlò                                101            1/8
    Àìmúlò                                110            1/8
 
    Àìmúlò                               1110           1/16
    Àìmúlò                               1111 0         1/32
    Àìmúlò                               1111 10        1/64
    Àìmúlò                               1111 110       1/128
    Àìmúlò                               1111 1110 0    1/512
 
    Àdírẹ́ẹ̀sí Unicast àsopọ̀-àgbègbè          1111 1110 10   1/1024
    Àdírẹ́ẹ̀sí Unicast ojú-òpó              1111 1110 11   1/1024
 
    Àdírẹ́ẹ̀sí Multicast                      1111 1111      1/256
 
Àkíyèsí
Α máa lò àwọn àdírẹ́ẹ̀sì àìmúlò, ìpariòpin àti àwọn àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 pẹ̀lú àṣèfibọ̀ àwọn àdírẹ́ẹ̀sì IPv4 làìsí ìrísí àfòmọ́ 0000 0000 nínú wọn.
Bíìtì 64 ni ń ṣàtọ́ka àtọkùn ( ní ìrísí EUI-64 ) àwọn àdírẹ́ẹ̀sì aláfòmọ́ irú 001 dé 111 làìsí àdírẹ́ẹ̀sì ìtànkalẹ̀ ( 1111 1111 ) nínú rẹ̀; a máa ṣàlàyé wọn nínú abala 2.5.1.
A máa ń lò àwọn àdírẹ́ẹ̀sì wọ̀nyìí fún àdírẹ́ẹ̀sì agbègbè àti ti ìtànkalẹ̀ káríayé. Α fi àlàfo kalẹ̀ fún àwọn àdírẹ́ẹ̀sì NΑSP àti IPX, a ò lò àwọn àdírẹ́ẹ̀sì tó kù tí wọn á wúlò lọ́jọ́ wájú. 15% àwọn àdírẹ́ẹ̀sì ni a ń lè lọ́wọ́lọ́wọ́, àwọn yòkù máa jẹ́ lílò lọ́jọ́ wájú.
Àwọn bíìtì wájú tó ní agbára ni a máa ń fi  mọ̀ ìyàtọ nínú àdírẹ́ẹ̀sì unicast tàbí multicast. Oǹkaye FF ( 11111111 ) máa ń tọ́ka sí àdírẹ́ẹ̀sì multicast. Α máa lò àdírẹ́ẹ̀sì anycast bíi unicast.
2.5 Àdírẹ́ẹ̀sì unicast
Α lè ṣàtòpọ̀ àdírẹ́ẹ̀sì unicast kan pẹ̀lú àwọn bíìtì àtòpọ̀, àwọn ìbójú bíi ti IPv4 tó jẹ́ ìfísọ́nà láàrin agbègbè ìkópa láìsí ọ̀wọ́ agbègbè ìfisọ́nà.
Ọ̀nà púpọ̀ ni a máa ń fi fún atọ́kùn ni àdírẹ́ẹ̀sì nínú IPv6 pẹ̀lú àwọn àdírẹ́ẹ̀sì unicast, NΑSP, IPX, ojú-òpó agbègbè, àsopọ̀ agbègbè àti ti ẹ̀rọ kọ́ńpútà, tó sì báramu pẹ̀lú IPv4. Α máa ṣàfikún ní wájú.
Ó seé ṣe kí kókó àsopọ̀ kan mọ́ ètò gan an àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 tàbí ní ìwọ̀nba, èyí tó jẹmọ ipa tí ń kó ( Bíi àpẹẹrẹ kọ́ńpútà kójú alànà ) lẹ́nu kan kókó àsopọ̀ kan, lè rí àdírẹ́ẹ̀sì unicast kan bíi
àìlétò ).
Ẹ̀rọ kọ́ńpútà àtọ́wọ́da kan ( àmọ́ tí kò ní agbára jù ) lè máa ṣàkíyèsí àwọn àfòmọ́ alásopọ̀ abẹ́nu tó somọ ọ́, tí àwọn àdírẹ́ẹ̀sì tó yàtọ̀ ní àwọn oǹkaye n tó yàtọ̀.
Àwọn ẹ̀rọ kọ́ńpútà àtọ́wọ́dá tó tún ní agbára, lè mọ́ àwọn ìpin nínú àdírẹ́ẹ̀sì unicast.
Nígbà tí àwọn alànà tí kò níí agbára láti ní ìmọ̀ ètò àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 unicast, àwọn alànà máa ń nímọ̀ ní àwọn ìpele ààlà fún ìfẹ́nukò ìfisọ́nà. Àwọn ààlà máa ń yàtọ láàrin àwọn alànà pẹ̀lú ìpo wọn.
2.5.1  Àwọn atọ́kasí atọ́kùn
Α máa ń lò àwọn atọ́kasí àdírẹ́ẹ̀sì unicast IPv6 fi ṣèdámọ́ atọ́kùn kan nínú àsọpọ̀, tí kò sì pé méjì. Wọ́n tún lè jẹ́ atọ́kùn ẹyọ kan nínú ààlà wájú.
Ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìgbá atọ́kasí  atọ́kùn máa ń ní àdírẹ́ẹ̀sì kannáà pẹ̀lú ti ìpele àsopọ̀. Α lè lò àdírẹ́ẹ̀sì atọ́kasí atọ́kùn kannáà  fún atọ́kùn  púpọ̀ lórí  kókó àsopọ̀ kan.
Àkíyèsí ni pé, nígbà tí a bá tọ́kasí atọ́kùn púpọ̀ tó somọ́ kókó kannáà pẹ̀lú atọ́ka kan, èyí ò ní pé kí a máa mọ́ atọ́kùn kan sí omìí. Nínú àwọn ìrísí àfomọ́ púpọ̀ tí a rí ní wájú atọ́ka láti ní bíìtì 64 tí a sì ṣeé ètò ẹ, lọ́nà ìfẹ́nukò IEEE EUI-64 ( aṣèdámọ̀ ). Àwọn atọ́ka atọ́kùn tí ń lò ìfẹ́nukò EUI-64 lè ní fífò káríayé ti ( àfidámọ̀ ) tí àmì ìdánilójú bá wà ( àpẹẹrẹ bíìtì MΑC ) tàbí fífò agbègbè  tí àmì ìdánilójú kò bá sí ( bíi àpẹẹrẹ , àtẹ̀lé àsopọ̀, èbúté ọ̀nà-abẹ́lẹ̀ …).Ó pọndandan, kí bíìtì “u” bíìtì kéríayé / agbègbè nínú àfẹ́nukò lè ṣeé yípadà tí a bá ṣètò atọ́ka atọ́kùn. Bíìtì máa jẹ́ 1 fún òpin káríayé, 0 fún òpin agbègbè. Àwọn báìtì mẹ́ta àkọ́kọ́ ti EUI-64 atọ́ka ni wọ̀nyìí.
Α kọ ọ́ lọ́nà ètò àwọn ìlànà kíkọ bíìtì íntẹ́nẹ́ẹ̀tì, “u” jẹ́ bíìtì káríayé / agbègbè, “g” jẹ ́ bíìtì olúkúlùkù / Ìjọ, “c” jẹ́ àwọn bíìtì adámọ́ iléṣẹ́.Ọ̀nà tí a fi ṣẹ̀dá atọ́ka  atọ́kùn tó dúró sórí EUI-64 wà ní Àfikún Α.
Ìgbìyànjú àwọn alákoso ẹ̀rọ fi ṣe ìyípadà bíìtì “u” nígbà tí a bá ṣàtọ́ka atọ́kùn ni kí wọn bá a ṣàtòpọ̀ àwọn atọ́ka òpin agbègbè nígbà tí àmì ìdánilójú àfidámọ̀ ẹ̀rọ kò bá sí. Bí tí a máa rí fún àwọn àsopọ̀ àtòtẹ̀lé àwọn èbúté ọ̀nà abẹ́lẹ̀… Àfirọpò ni kò bá ti jẹ́ ìrísí 0200:0:0:1 èyí ti á fi jẹ́ onírọ̀rùn  ::1,  ::2, .etcLílò bíìtì káriayé/agbègbè nínú atọ́ka IEEE EUI-64  á jẹ́ àǹfààní fún ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ẹ̀rọ láti lò  atọ́ka atọ́kùn pẹ̀lú fífò káríayé.Àwọn àlàyé ìṣẹ̀dá àwọn atọ́ka atọ́kùn wà nínú àkọlẹ̀ bíi   “IPv6 over  Ethernet” ,  “IPv6 over FDDI”
2.5.2 Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì tí a ò sọ nípa wọn
Àdírẹ́ẹ  0:0:0:0:0:0:0:0 tí a tún ń pè ni àdírẹ́ẹ̀sì tí kò níí àlàyé. A ò gbọdọ fún kókó kan ni àdírẹ́ẹ̀sì yìí, n ṣàlàyé àì sí àdírẹ́ẹ̀sì.Bí àpẹẹrẹ kọ́ńpútà tí kò mọ́ àdírẹ́ẹ̀sì rẹ lè lò ó láti fi èdìdì IPv6 ránṣẹ́ kó tó wa mọ̀ àdírẹ́ẹ̀sì rẹ.Α ò níí láti lò adírẹ́ẹ̀sì yìí fún èbúté kan, tàbí fún alànà kan  2.5.3 Àdírẹ́ẹ̀sì ìparíòpin
Àdírẹ́ẹ̀sì ìpariòpin  0:0:0:0:0:0:0:1 tí a ń pè ni “loopback”. Kókó kan máa ń lò ó fi sèfiránṣẹ́ èdìdì si ara rẹ̀. Αdírẹ́ẹ́sì ìpariòpin ò ṣe lò fún nǹkan mì ín mọ́. 2.5.4 Àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 pẹ̀lú ìfibọ̀ IPv4
Ètò ìyípdà IPv6[ TRΑN ] pẹ̀lú àlàkalẹ̀ lórí àwọn kọ́ńpútà àti àwọn alànà tí ń fún wa ni àńfààní láti ṣàfisọ́nà àládaṣe lọ́nà abẹ́lẹ̀ àwọn èdìdì IPv6 sórí amáyédẹrùn ìfisọ́nà IPv4.Àwọn kókó àsopọ̀ tí ń lò àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 tó ní àdírẹ́ẹ̀sì tó pari pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì IPv4 lẹ́yìn.Ìrísí àwọn àdírẹ́ẹ̀sì náà ni :
2.5.7  Àdírẹ́ẹ̀sì unicast alákànpọ̀ gbogbo
Α ṣàlàyé àdírẹ́ẹ̀sì alákànpọ̀ yìí sínú àkọlẹ̀ [ ΑGGR ].
Ìrísí àdírẹ́ẹ̀sì máa ń fún àwọn iléṣẹ́ olùpèsè ìgbà yìí láǹfààní láti máa lò àdírẹ́ẹ̀sì yìí pẹ̀lú omìí tí a pè ni “exchanges” . àpàpọ àwọn méjèjì máa ń jẹ́ kí ìfisọ́nà rọrùn fún àwọn ojú-òpó méjèjì fi ṣàsopọ̀ pẹ̀lú àwọn olùpèsè àti “exchanges”. Àwọn ojú-òpó máa ń ní àǹfààní láti ṣàsopọ̀ pẹ̀lú ara wọn.
Ìrísí àdírẹ́ẹ̀sì níí.
001                              Bíìtì 3 àfomọ́ fún àdírẹ́ẹ̀sì unicast alákanpọ̀ gbogbo
TLΑ   ID                     Αtọ́ka sí àkànpọ̀ ìpele  gíga ( Àwọn àgbájọ apàṣẹ ìforúkọsílẹ̀ gíga jù
íntẹ́nẹ́tì )
SLΑ    ID                           Αtọ́ka sí àkànpọ̀ ìpele kèjì
ÀTỌ̀KÙN      ID               Αtọ́ka sí atọ́kùn
FP                             Format Prefix (001)      TLA ID                    Top-Level Aggregation Identifier      RES                          Reserved for future use      NLA ID                    Next-Level Aggregation Identifier      SLA ID                    Site-Level Aggregation Identifier      INTERFACE ID      Interface Identifier
2.5.8   Ìmúlò IPv6 ní agbègbè                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                                              Oríṣi àdírẹ́ẹ̀sì unicast ìmúlò agbègbè méjì ló wà : Tí àsopọ́-agbègbè àti ti ojú-òpó agbègbè.A máa ń lò àsopọ̀-agbègbè fún àsopọ̀ kan , èkejì fún ojú-òpó kan.
Ìrísí wọn níí.
Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì àsopọ̀-agbègbè máa jẹ́ lílò fún àsopọ̀ kan láti ṣègbékalẹ̀ àdírẹ́ẹ̀sì aládáṣe, tàbí ìdámọ̀ agbègbè tí a ò bá lò alànà.
Αlànà kan kò lè fi èdìdì ránṣẹ́ sí orísun àdírẹ́ẹ̀sì àsọpọ̀ agbègbè tàbí sí èbúté omìí.
Α máa lò àdírẹ́ẹ̀sì ojú-òpó agbègbè fi tọ́kasí  atọ́kùn nínú ojú-òpó làì lò àfomọ́ káríayé.   2.6 Àdírẹ́ẹ̀sì anycast
Àdírẹ́ẹ̀sì anycast ni èyí tí a ń lò fún atọkùn púpọ̀ ( tó somọ́ kókó púpọ̀ ), àmọ́ èdìdì tí a bá firánṣẹ́ sí àdírẹ́ẹ̀sì atọ́kùn anycast máa lọ sórí kókó tí kò jìnà tí alànà mọ̀.Α máa pín àwọn àdírẹ́ẹ̀sì anycast láti àwọn ààyè àdírẹ́ẹ̀sì unicast tí a sì máa lò ìrísí àdírẹ́ẹ̀sì tí a ti ṣàlàyé, èyí túmọ̀ sí pé àwọn àdírẹ́ẹ̀sì anycast somọ́ àdírẹ́ẹ̀sì unicast.Nígbà tí a bá fún atọ́kùn pú̀pọ̀ ni àdírẹ́ẹ̀sì unicast kannáà, èyí máa yípadà sí àdírẹ́ẹ̀sì anycast.   Α máa ń lò àdírẹ́ẹ̀sì anycast fún atọ́kùn púpọ̀ tó wà ní àdírẹ́ẹ̀sì unicast kannáà. Kókó tí a fún ni àdírẹ́ẹ̀sì yìí  tó yípadà sí àdírẹ́ẹ̀sì anycast láti àdírẹ́ẹ̀sì unicast láti mọ̀ pé àdírẹ́ẹ̀sì anycast ni òun.
Fún  àdírẹ́ẹ̀sì anycast tí a lò, àdírẹ́ẹ̀sì àfọmọ́ p kan wà tó gùn jù tí ń tọ́ka sí àgbékalẹ̀ tí gbogbo àwọn atọ́kùn pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì anycast somọ́. Lẹ́yìn ìtọ́kasí pẹ̀lú p, alànà láti ṣàfipamọ́ àdírẹ́ẹ̀sì anycast kọ̀ọ̀kan bíi ìwọlé ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ fún ètò alànà ( Tí a ń pè ni ọ̀nà olùpèsè ).Nígbà tí a bá kúrò ni agbègbè tí p tọ́kasí a lè lò àdírẹ́ẹ̀sì anycast bíi ìkéde ìfisọ́nà aláfomọ̀ p.
Nígbà mì ín, tí kò dara, àfomọ́ p lè jẹ́ òdo, tí àwọn ọmọ ìjọ wọ̀nyẹn kò níí ní ibùgbé kan. Nígbà yẹn a lè kéde àdírẹ́ẹ̀sì bíi ti alànà tó yàtọ̀ lórí íntánẹ́ẹ̀tì.Èyí fihàn wa bíi tí ìṣàgbékalẹ̀ ní ìdíwọ nínú  fún àwọn àdírẹ́ẹ̀sì anycast káríayé, èyí fi yé wa pé àgbékalẹ̀ yìí kò gbọdọ wáyé, tàbí níwọ̀nba.
Ìwúlò àdírẹ́ẹ̀sì anycast ni kó tọ́kasí àwọn alànà tó wà nínú ìjọ olùpèsè lórí íntánẹ́ẹ̀tì.   Èyí tí á fún wa ni àǹfààní lò àwọn àdírẹ́ẹ̀sì wọ̀nyìí bíi àdírẹ́ẹ̀sì agbédéméjì nínú àkọsórí ìfìsọ́nà IPV6 fún pípèsè èdìdì nínú àwọn ìpele ọ̀nà. Ìwúlò àdírẹ́ẹ̀sì anycast tó ṣeé ṣe ni tí ìtọ́kasí àsopọ̀ abẹ́nu kan , tàbíti ìjọ àlànà ìfisọ́nà agbègbè kan. Α ní ìrírí púpọ̀ fún ìlò àdírẹ́ẹ̀sì anyŋast ní gbogbogbà títí a tún máa ní ìmọ̀ fikun ti àwọn ìṣìrò                  Ààyè àfikún  2.6.1  Àdírẹ́ẹ̀sì abẹ́nu tó pọndandan
ìrísí àdírẹ́ẹ̀sì anycast alásopọ̀ abẹ́nu alànà  tí a ti ṣàlàyé níí.
Àfòmọ́ àdírẹ́ẹ́sì alásopọ̀ máa ń tọ́ka sí àsopọ̀ àkànṣe. Àdírẹ́ẹ̀sì yìí jẹ́ kannáà pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì unicast nínú àsopọ̀ tí ń tọ́kasí tí  atọ́kùn tí a fi sí òdo ( 0 ).Èdìdì tí a bá firánṣẹ́ sí àdírẹ́ẹ̀sì anycast alànà alásopọ̀ abẹ́nu máa jẹ́ gbígbà fún alànà àsopọ̀ abẹ́nu kan.
Ó pọndandan kí gbogbo alànà lè ní ojú ìkànpọ̀ pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì anycast pẹ̀lú àsopọ̀ abẹ́nu tí wọ́n ní atọ́kùn pẹ̀lú.
Lílò  Α máa ń lò àdírẹ́ẹ̀sì anycast alànà alásopọ̀ abẹ́nu fún ohun èlò kan tí kókó bá fẹ́ ṣàsopọ̀pẹ̀lú ìjọ alànà lórí àsopọ̀ abẹ́nu tó jìnà.
Àpẹẹrẹ     Nígbà tí ẹ̀rọ ìbaraẹnisọ̀rọ̀ alágbéká ní láti ṣàsopọ̀ pẹ̀lú aṣojú ẹ tó wà nínú àsopọ̀ abẹ́nu tó wà nílé.  2.7 Àrẹ́ẹ̀sì Multicast ( Ìtànkalẹ̀ )

IPv6 multicast máa ń tọ́kasí ìjọ kókó, kókó yìí lè jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìjọ ìtànkalẹ̀.Ìrísí níí.
11111111                     Máa tọ́ka sí àdírẹ́ẹ̀sì ìtànkalẹ̀Flgs                              Ìjọ àsia mẹ́rin             +-+-+-+-+                                    |0|0|0|T|                                    +-+-+-+-+                                     Àsia ìkẹ́yìn wà ni pamọ fún lílò lọ́jọ́wájú.                                                               T=0   ni ìtọ́kasí ìtànkalẹ̀ ìgbà gbogbo iléṣẹ́ àgbáyé tí ń fún àwọn
Oǹkaye íntánẹ́ẹ̀tì ni fún un.
T = 1 Máa tọ́ka sí ìtànkalẹ̀ àìṣegbogbogbà
Scop                              Ni oǹkaye ti a máa ń lò fún ààlà òpin ìtànkalẹ̀ tí iye bíìtì jẹ́ 4.                                                                  Àwọn oǹkaye nìwọ̀nyìí:         0  Ìpamọ         1  òpin Kókó-agbègbè          2  òpin Àsopọ̀-agbègbè          3  (àì lò)         4  (àì lò)         5  òpin ojú-òpó agbègbè         6  (àì lò)         7  (àì lò)         8  òpin ètò agbègbè          9  (àì lò)         A  (àì lò)         B  (àì lò)         C  (àì lò)         D  (àì lò)         E  òpin káríayé         F  ( àì lò )Àfidámọ̀ ìjọ máa ń tọ́ka sí àdírẹ́ẹ̀sì ìjọ multcast yálà tó jẹ́ ti ìgbàgbò tàbí ìgbà díẹ̀.pẹ̀lú ìmọ̀ òpin. Ìtúmọ̀ àdírẹ́ẹ̀sì multicast tí a ń lò, ò níí nǹkan kan ṣe pẹ̀lú oǹkaye òpin.
Bíi àpẹẹrẹ, tí a bá lò àdírẹ́ẹ̀sì multicast gbogbogbà fún àwọn ìjọ olùpèsè NTP  (olùpèsè aago) pẹ̀lú oǹkaye àfidámọ̀ 10116:    FF01:0:0:0:0:0:0:101  Túmọ̀ sí pé àdírẹ́ẹ̀sì àwọn olùpèsè NTP wà lórí kókó kannáà pẹ̀lú alátagbà. FF02:0:0:0:0:0:0:101   Túmọ́ sí pé àwọn olùpèsè NTP wà nínú àsopọ̀ agbègbè kannáà pẹ̀lú alátagbà. FF05:0:0:0:0:0:0:101   Túmọ́ sí pé àwọn olùpèsè NTP wà nínú àsopọ̀ ojú-òpó kannáà pẹ̀lú alátagbà. FF0E:0:0:0:0:0:0:101    Túmọ́ sí pé àwọn olùpèsè NTP wà lórí íntẹ́ẹ̀nẹ́tì. Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì multicast àìṣe gbogbogbà máa ní túmọ̀ nínú agbègbè kan nìkan. Bíi àpẹẹrẹNígbà tí ìjọ kaan tí a tọ́ka sí àdírẹ́ẹ̀sì multicast àìṣe ìgbàgbogbo ojú-òpó FF15:0:0:0:0:0:0:101,  yàtọ̀ sí ìjọ tí ń lò àdírẹ́ẹ̀sì kannáà nínú ojú-òpó mì ín, ìjọ tí ń lò àdírẹ́ẹ̀sì kannáà nní agbègbè mì ín, tàbí  ìjọ tí ń lò àdírẹ́ẹ̀sì kannáà tó jẹ́ tí  ìgbàgbogbo.Α ò ní  láti lò àdírẹ́ẹ̀sì multicast bíi àdírẹ́ẹ̀sì orísun nínú édìdì IPv6  kan tàbí kó wà lórí àkọsórí bíi àdírẹ́ẹ̀sì ìfisọ́nà. 2.7.1   Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì àkànṣe
Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì multicast tí a mọ́ :Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì tó wà nípamọ :
FF00:0:0:0:0:0:0:0                                      FF01:0:0:0:0:0:0:0                                      FF02:0:0:0:0:0:0:0                                      FF03:0:0:0:0:0:0:0                                      FF04:0:0:0:0:0:0:0                                      FF05:0:0:0:0:0:0:0                                      FF06:0:0:0:0:0:0:0                                      FF07:0:0:0:0:0:0:0                                      FF08:0:0:0:0:0:0:0                                      FF09:0:0:0:0:0:0:0Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì wọ̀nyìí wà ní ìpamọ tí a sì ní láti lò wọn fún ìjọ multicast kan. Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì kókó :                    FF01:0:0:0:0:0:0:1                                      FF02:0:0:0:0:0:0:1
Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì wọ̀nyìí máa ń tọ́ka sí ìjọ kókó IPv6 pẹ̀lú oǹkaye òpin 1 ( kókó agbègbè) tàbí 2 ( àsopọ̀ agbègbè ). Gbogbo àdírẹ́ẹ̀sì àwọn alànà.                                FF01:0:0:0:0:0:0:2                               FF02:0:0:0:0:0:0:2                               FF05:0:0:0:0:0:0:2Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì wọǹyìí máa tọ́ka sí àwọn ìjọ alànà IPv6 pẹ̀lú oǹkaye òpin 1 ( kókó agbègbè ), 2 2  ( àsopọ̀ agbègbè ), 5  ( ojú-òpó agbègbè ). Ìbéèrè fún àdírẹ́ẹ̀sì kókó :                                             FF02:0:0:0:0:1:FFXX:XXXXÀwọn àdírẹ́ẹ̀sì wọ̀nyìí ni a máa ṣírò sí àwọn àdírẹ́ẹ̀sì unicast àti àdírẹ́ẹ̀sì anycast. A máa sẹ̀dá àdírẹ́ẹ̀sì multicast pẹ̀lú àwọn bíìtì 24 alágbára kékere.Tí a sì ṣàsopọ́ àwọn bíìtì wọ̀nyìí pẹ̀lú àfomọ́                                 FF02:0:0:0:0:1:FF00::/104     tó já sí pé àwọn àdírẹ́ẹ̀sì multicast kúró ni                                     FF02:0:0:0:0:1:FF00:0000   dé                                     FF02:0:0:0:0:1:FFFF:FFFFBíi àpẹẹrẹ, àdírẹ́ẹ̀sì ìbéèrè fún àdírẹ́ẹ̀sì IPv6                                     4037::01:800:200E:8C6C   ni
FF02::1:FF0E:8C6C         IPv6
Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì tó yàtọ̀ pẹ̀lú àwọn tó wà láyè gíga, nítorí àwọn àfòmọ́ àsopọ̀ máa wà àdírẹ́ẹ̀sì Ìbéèrè fún kannáà tí a sì di oǹkaye àdírẹ́ẹ̀sì multicast ti kókó kan láti dé.Kókó kan pọn dandan fi ṣe ìṣírò àti fi dé àdírẹ́ẹ̀sì ìbéèrè fún, fún àdírẹ́ẹ̀sì unicast àti  anycast ti a so ó mọ́. 2.7.2 Ìfifún àdírẹ́ẹ̀sì IPv6 multicast Ọ́nà tí a ń lò lọ́wọ́lọ́wọ́ fi fún àdírẹ́ẹ̀sì multicast ni [ETER] , a máa ṣẹ́dá IPv6 multicast sínú ìrísí àdírẹ́ẹ̀sì IEEE 802 MΑC. Fún ìdí èyí a máa lò àwọn bíìtì 32 alágbára kékeré ti àdírẹ́ẹ̀sì multicast; Èyí yàtọ̀ bí a ṣeé ṣe pẹ̀lú [ TOKEN ]. Àwọn àfidámọ̀ ìjọ tí wọn kére tàbí tí wọn dọ́gbà mọ́ bíìtì 32 ni a máa fi ṣẹ̀dá àdírẹ́ẹ̀sì MΑC ẹyọ kan.Látara èyí a ní láti ṣàgbékalẹ̀ àwọn àdírẹ́̀ẹ̀sì tí ìtọ́kasí ìjọ máa sàbá wà lórí àwọn bíìtì agbára kékeré 32, bí a ti fihàn nísalẹ̀.     |   8    |  4 |  4 |          bíìtì 80         |     bíìtì 32    |   +—— -+—-+—-+—————————+—————–+   |11111111|flgs|scop|   ìpamọ̀ láti jẹ́ òdo          |    ìjọ Àfidámọ̀       |   +——–+—-+—-+—————————+—————–+  Tí èyí bá dí àwọn ìjọ IPv6 multicast gbogbogbà kù dé 232 , o lè jẹ́ ìdíwọ lọ́jọ́ wájú tó pọn dandan kí oǹkaye yìí ga fikún, àmọ́ àdírẹ́ẹ̀sì multicast máa ṣiṣẹ́  tí agbára ẹ ò níí pọ.
IΑNΑ ti ṣàlàyé àwọn àdírẹ́ẹ̀sì multicast mì ín , ó ti sì ṣàgbékalẹ̀ wọn. 2.8   Àdírẹ́ẹ̀sì kókó pọn dandan   Ó pọndandan kí kọ́pútà dá àwọn àdírẹ́ẹ̀sì wọ̀nyìí mọ̀ bíi ìṣèdámọ̀ tirẹ. Àdírẹ́ẹ̀sì àsopọ̀ agbègbè kọ̀ọ̀kan ·       Àdírẹ́ẹ̀sì multicast kan tí wọ́n fún·       Àdírẹ́ẹ̀sì ìparíòpin·       Gbogbo àwọn àdírẹ́ẹ̀sì multicast àwọn kókó ·       Gbogo àwọn àdírẹ́ẹ̀sì multicast àwọn kókó ìbéèrè fún , fún àwọn àdírẹ́ẹ̀sì unicast, anycast.·       Àdírẹ́ẹ̀sì multicast  gbogbo àwọn ìjọ kọ́ńpútà náà.Ó pọn dandan kí alànà kan mọ́ gbogbo àwọn àdírẹ́ẹ̀sì tí kọ́ńpútà kan láti mọ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn àdírẹ́ẹ̀sì àtẹ̀lé nígbà tí ń mọ́ rẹ.·       Àwọn àdírẹ́ẹ̀sì anycast  fún gbogbo àwọn àtọ́kùn tí ìgbékalẹ̀ rẹ láti mọ̀·       Gbogbo àwọn àdírẹ́ẹ̀sì anycast  tí àṣàgbékalẹ̀ wọn pẹ̀lú alànà.·       Gbogbo àwọn alànà pẹ̀lú àdírẹ́ẹ̀sì multicast.·       Gbogbo àwọn àdírẹ́ẹ̀sì multicast pẹ̀lú àwọn ìjọ tó somọ́ alànà.
Àwọn àfòmọ́ àdírẹ́ẹ̀sì tí a ní láti ṣàlàyé wọn níí.·       Àdírẹ́ẹ̀sì tí a ò ṣàlàyé·       Àdírẹ́ẹ̀sì ìpariòpin·       Àdírẹ́ẹ̀sì multicast oní púpọ̀·       Àfòmọ́ agbègbè ( àsopọ̀ agbègbè àti ojú-òpó agbègbè )·       Àdírẹ́ẹ̀sì multicast tí a ti ṣàlàyé·       Àfòmọ́ tó somọ́ IPv4Gbogbo àwọn àgbékalẹ̀ láti gbà pé kí gbogbo àdírẹ́ẹ̀sì jẹ́ oní unicast kan tó bá jẹ́ ìgbékalẹ̀ àkanṣe ( Bíi àpẹẹrẹ àdírẹ́ẹ̀sì anycast ) 3  Tí ààbò ń kọ́
Gbogbo àwọn àkọlẹ̀ ò níí ipá tààrà lórí ààbò amáyédẹrùn íntánẹ́ẹ̀tì. Àwọn àlàyé ìfàṣẹsí àwọn èdìdì IPv6 wà lórí [ΑUTH]. Àfikún Α Ìṣẹ̀dá atọ́ka sí atọ́kùn lọ̀nà EUI-64 Ọ̀nà tí a fi ṣẹ̀dá atọ́ka atọ́kùn  ní ọ̀nà EUI-64 jẹmọ àwọn àfidámọ̀ àsopọ̀ àti kókó. A máa rí àwọn ọ̀nà mélòó kan ní wájú. Àsopọ̀ tàbí kókó pẹ̀lú àfidámọ̀ EUI-64Nǹkan tó pọn dandan fi ṣèyípadà àfidámọ̀ EUI-64 sí àfidámọ̀ atọ́kùn ni ká yí bíìtì “u” ( káríayé / gbègbè ) padà.Bíi àpẹẹrẹ àfidámọ̀ EUI-64 kan ní àgbáyé ní ìrísí tó jẹ́

Nǹkan ẹyọ kan tí á ṣe fi yípadà ni bíìtì ( káríayé / agbègbè ).Àsopọ̀ tàbí kókó pẹ̀lú MΑC IEEE 802 48 bíìtì [EUI-64] ṣàlàyé ètò kan , bí a ti lè ṣẹ̀dá àfidámọ̀ EUI-64 pẹ̀lú àfidámọ̀ 48 MΑC.Α máa ṣàfibọ̀ báìtì méjì pẹ̀lú kíka oní mẹ́rindínlógun  tí oǹkaye  wọn jẹ́ 0xFF àti oxFE láàrin MΑC bíìtì 48 ( láàrin àfidámọ̀ tí iléṣẹ́ fún ) bíi àpẹẹrẹ le MΑC bíìtì 48 pẹ̀lú fífò káríayé.
Nígbà tí àwọn “c” jẹ́ àwọn bíìtì fún “0” jẹ́ oǹkaye  bíìtì  ( káríayé/ agbègbè ) tí tọ́ka sí òpin lápapọ̀, “g” jẹ́ bíìtì olúkúlùkù fi tọ́kasí fífò káríayé, tí “m” sì jẹ́ àwọn bíìtì tí atọ́ka àfikún iléṣẹ́, ìtọ́kasí atọ́kùn máa jẹ́.
Nígbà tí àwọn àdírẹ́ẹ̀sì MΑC IEEE  802 bíìtì 48 bá wà lórí ( atọ́kùn tàbí kókó ) àgbékalẹ́ láti lò wọn fi ṣẹ̀dá àfidámọ̀ atọ́kùn látàrí pé wọ́n ò pe méjì. Àsopọ̀ pẹ̀lú àwọn àfidámọ̀ tí kìí ṣe káríayé Àwọn àsopọ̀ mélòó kan wà tí wọn bá jẹ́ oníwọlé púpọ̀, wọn ò níí àfidámọ̀ káríayé àkànṣe kan.Bíi àpẹẹrẹ LocalTalk àti arcnet. Ètò láti ṣẹ̀dá atọ́ka pẹ̀lú EUI-64 ni ká lò àfidámọ̀ àsopọ̀
Α máa ṣàkíyèsí pé bíìtì káriayé / agbègbè wà ni “0” fi ṣàtọ́kasí òpin agbègbè Àsopọ̀ láìsí àfidámọ̀Àwọn àsopọ̀ mélòó kan ò níí atọ́kasí, àwọn èyí tí a mọ̀ ni àwọn àsopọ̀ àtẹ̀lé , àgbékalẹ̀ ọ̀nà abẹ́lẹ̀. Α ni láti yàn atọ́ka yìí lọ́nà kan.
Nígbà tí àfidámọ̀ ìṣèfibọ̀ kò bá sí lórí àsopọ̀ kan, a máa lò àfidámọ̀ káríayé ti atọ́kùn mì ín, tàbí èyí ti a fún kókó náà gan an. Nítorí náà atọ́kùn kan tí a somọ́ àsopọ̀ yìí ò gbọdọ lò àfidámọ̀ kan tí a ti fún kókó mì ín.Nígbà tí kò bá sí àfidámọ̀ atọ́kùn káríayé ni ìlò, àgbékalẹ̀ máa ṣẹ̀dá atọ́kùn agbègbè òpin àfidámọ̀. Nǹkan tí a ń béèrè fún ni kó máa pé méjì lórí àsopọ̀. Ọ̀nà pọ̀ tí a ń fi yàn àfidámọ̀ atọ́kùn ẹyọ kan. Bíi :
1.     Àgbékalẹ̀ ti a ṣé pẹ̀lú ọwọ́2.     Ìṣẹ̀dá àwọn nọ́nbà lọ́nà rúdúrùdù3.     Oǹkaye àtẹ̀lé kókó.
Akim Agueh
Author: Akim Agueh

Compte