Non classé
Ìpàrokò àti VPN ( web security )
Web security Ìpàrokò; VPN; IPSEC
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọrọ ìpele èkèjì
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọrọ ìpele èkèjì
Ìṣèdọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní
Ìṣedọ́gba yíyàtọ̀ onígbọọrọ ìpele èkíní
Ọsílósíkọ́pù
Ọsílósíkọ́pù Ọsílọ́síkọ́pù jẹ́ ẹ̀rọ tí máa ń fún wa ni àǹfààní láti wọn àwọn ohun agbára, tí a á sì ṣàfihàn àwòrán àmì wọn lórí aṣàfihàn lọ́nà ìbàtan pẹ̀lú àsìkò, Α máa rí àmì yìí pẹ̀lú àwọn ìtọ́kasí t àti y lórí ọsílósíkọpù. Α máa ń rí àwọn ìlà tí ìrísí wọn jẹmọ́ ìṣe mathimátíkì …
Ìmọ̀ ojú àmì ìṣiṣẹ́ Ìṣípòtakò
Ìmọ̀ ojú àmì ìṣiṣẹ́ transitọ ( Ìṣípòtakò ) 1 Ìmúlò àwọn ìlà àfidámọ̀ Ìṣípòtakò ( Transitọ ) 1.1 Àwárí ojú àmì ìṣiṣẹ́ ìṣipòpadà ( transitọ ) A máa ń lò àwọn àfidámọ̀ àwọn trànsitọ fi mọ̀ ojú àmì ìsiṣẹ́ wọn. Èyí máa jẹ́ ká mọ̀ àwọn agbára iná mànàmáná tí a ń lò. Àwọn àfidámọ̀ …
Java àkójọpọ̀ Orí 2
Àwọn ọ̀wọ́ Àwọn ọ̀wọ́ ní àwọn àfidámọ̀ àti àwọn àlàkalẹ̀. Àwọn àfidámọ̀ jẹ́ àwọn oníyípadà àwọn ohun ọ̀wọ́ ( ìsọ̀wọ́ ), nínú ọ̀wọ́ a tún máa ri àwọn ètòlẹ́sẹẹsẹ tí wọn sì jẹ́ àwọn àlàkalẹ̀ ìṣe. Fún àwọn ohun ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan àwọn àlàkalẹ̀ jẹ́ ọ̀kan náà, àmọ́ àwọn ìsọfúnni tó jẹ́ àwọn oníyípadà ló yàtọ̀. …
Αlúgórídímù
Ẹ̀kọ́ Αlúgórídímù Αlúgórídímù Nígbà tí a bá fẹ́ kọ alúgórídímù, ìgbésẹ̀ mẹ́ta ni a máa ń gbé. I Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́ta náà ni 1.1 ) Ìgbésẹ̀ kìíní Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí a ṣàlàyé àwọn ohun ti a fẹ́ lò ( Àwọn oníyípadà, ìró , nọ́ḿbà..) 1.2 ) Ìgbésẹ̀ kejì A máa tú ìṣòro wa sí …
Alákójọpọ̀ Java
Java Akójọpọ̀ Java Compiler Java Compilateur Orí 1 I Ìbẹ̀rẹ̀ Java jẹ́ ètòlẹ́sẹẹsẹ alákójọpọ̀ ti máa ń fún wa ni àǹfààní láti kọ ohun èlò ètò oríṣiríṣi, ó sì tún jẹ́ ètò alákójọpọ̀ tó tẹ̀ síwájú. Ọ̀nà méjì ni a ń fi kọ ohun èlò kọ́ńpútà pẹ̀lú Java …
Semikọ́ndọ́kítọ̀
Semikọ́ndọ́kítọ̀ Semiconductor Semiconducteur Àwọn adàìtanná-níwọ̀nba ( Semikọ́ndọ́kítọ̀ ) Ìbẹ̀rẹ̀ Inú ohun ìṣẹ̀da kan a lè rí bíi bílíọ́nù ọ̀nà bílíọ́nù atómù ( èròjà akéréjojú ) (ọta). Αtómù ní kúró ti àwọn ìtanná ( elekítírónì ) máa ń yí àyíká ẹ. Kúró yìí tún ní àwọn èròjà ” kékere méjì …