Ìpàrokò àti VPN

1 Ọ̀rọ̀ ìṣáájú Ìpàrokò ni ohun èlò ti a máa sàbá lò fi dáàbòbò àwọn ìsọfúnni. Nígbà gbogbo Αlúgórídímù ìpàrokò ni a ń lò fi  pàrokò àti ìṣàtúpalẹ̀ àrokò. Àwọn alúgórídímù wọ̀nyìí máa ń lo ìṣòro ìṣírò tó le láti rí abájáde rẹ̀, bìi ìsọdipúpọ̀ àwọn nọ́mbà àkọ́kọ́, àwọn alúgórídímù afọyè wò. Kọkọrọ ìpàrokò àti …

Ìpàrokò àti VPN Lire la suite »